Shola Allyson Oro Oluwa Lyrics

Want create site? Find Free WordPress Themes and plugins.

Shola Allyson Oro Oluwa Lyrics

Oro oluwa koni lo laise

Ife oluwa koni lo laise

Imo oluwa koni lo laise

 

Ooun mori ye ko ba mi leru

Oun mori ye mimi lokan

Oti le ye ko fo mi laya

Sugbon mo pinu lati diimu olorun ododo ni

Siibe mo pinu lati mokanro tori mo mo pe oro

 

Oluwa koni lo laise

Ife oluwa koni lolaise

Imo oluwa koni lo laise

 

Ibanuje le wa sibe oro re a se

Ikoro le po sugbon adun la ja si

Mogboju mi sa pa oke

Ironwo mi be lati odo olorun ododo

Idaniloju yi mu reti wa tori mo mope

Oro re si mi koni lo laise

Ife re si mi rereni ko ni lo laise

Iimo oluwa koni lo laise

 

Olorun kin se eniyan to ma se ke

Oti wi be a se be dandan lo je

Bo ti le wun kori oro re ase

Ole pe die sugbon ko ye uhnuhn rara rara

Ofifo a dopo irora adi irorun ka ni ireti

Adun a po a pe agbirigidi afe a pe

Igbagbo re ko ma pin se ileri ase

Igbagbo re ko ma pin se ileri ase

Igbagbo re ko mi se ileri a se

 

Ooun mori ye ko ba mi leru

Oun mori ye mimi lokan

Oti le ye ko fo mi laya

Sugbon mo pinu lati diimu olorun ododo ni

Siibe mo pinu lati mokanro tori mo mo pe oro

Oluwa koni lo laise

Ife oluwa koni lolaise

Imo oluwa koni lo laise

 

O ko j ope o buro ni ko ni buru si o koni lo laise

Mo ju kuro ninu juju to yi o ka iranwo a wa koni lo laise

Ohun nil owo iranlowo igba to wa ati igba ti o wa oro re ko ni lo liase

Alolugba aloluto gba ati olu dari mi oro re rere ni e oro

Oluwa koni lo laise

Niwon igba ti mo gbekele oluwa emi o ni ri itijukan lailai koni lo laise

Mo gba lolu ran lowo ohun lo ran mi lowo oro re koni lo laise

Oti wi be a se be fun mi mo duro mo duro koni lo laise

E oro oluwa koni lo laise koni lo laise

Gbabe koni lo laise

Oro re si wa rere koni lo laise

Tuju re ka koni lo laise

Labe bo ti wun kori gba gbe koni lo laise

Oro oluwa ko ni lo layi se

Shola Allyson Oro Oluwa Lyrics

Did you find apk for android? You can find new Free Android Games and apps.

Leave a Comment