Shola Allyson Eji Owuro Lyrics

Want create site? Find Free WordPress Themes and plugins.

Shola Allyson Eji Owuro Lyrics

Duro timi o, ololufe

Ife ti ko labuku ni ko ba mi lo

Duro timi o, Ololufe

Ife ti ko labawon ni ko ba mi lo

Ife bi Eji Owuro,

latagbala Eledumare lo ti se wa

Ife to tooro minimini,

Tabawon aye kan o le ba je o

Ololufe feran mi laisetan

Ife bi Eji Owuro,

latagbala Eledumare lo ti se wa

Ife to tooro minimini,

Tabawon aye kan o le ba je o

Ololufe feran mi laisetan

Femi bi oju ti n f’emu

Femi bi irun ti n f’ori

Femi bi eyin ti n f’enu

Femi teerin teerin

Femi taayo taayo

Femi taara taara

Ololufe feran mi laisetan

Ife bi Eji Owuro,

latagbala Eledumare lo ti se wa

Ife to tooro minimini,

Tabawon aye kan o le ba je o

Ololufe feran mi laisetan

Ba mi s’ootito, Mo fe o tooto

Ba mi s’ododo, Mo fe o pelu ododo

Ba mi s’ootito, (Ololufe) Mo fe o tooto

Ba mi s’ododo, Mo fe o pelu ododo

B’ogiri o ba la’nu, Alangba o le w’ogiri

B’ogiri o ba la’nu, Alangba o le w’ogiri

Eleda lo yan wa papo, Esu ko ni yawa o

Ife bi Eji Owuro,

latagbala Eledumare lo ti se wa

Ife to tooro minimini,

Tabawon aye kan o le ba je o

Ololufe feran mi laisetan.

A ma lowo lowo

A ma kole mole

A ma bimo lemo

A ma sayo mayo

A ma shola mola

Ka sa mufe Eledumare se, laisetan.

A ma lowo lowo

A ma kole mole

A ma bimo lemo

A ma sayo mayo

A ma shola mola

Ka sa mufe Eledumare se, laisetan.

Ife bi Eji Owuro,

latagbala Eledumare lo ti se wa

Ife to tooro minimini,

Tabawon aye kan o le ba je o

Ololufe feran mi laisetan.

Gb’amoran mi, Ololufemi!

Oluranlowo la fi mi se fun o lat’orun wa

F’eti s’amoran mi, ololufemi!

Oluranlowo la fi mi se fun o lat’orun wa

Kaj’orin ka s’ogo, l’oruko olorun

Alabinrin la fi mi se fun o lat’orun wa

M’okan ku ro ni asan aye

Etan o da n kankan fun ni

Ife at’ope lo le mu wa l’aye ja lai labawon

M’okan ku ro ni asan aye

Etan o da n kankan fun ni

Ife at’ope lo le mu wa l’aye ja lai labawon

Ife bi Eji Owuro,

latagbala Eledumare lo ti se wa

Ife to tooro minimini,

Tabawon aye kan o le ba je o

Ololufe feran mi laisetan.

Duro timi o, Ololufe

Ife ti ko labuku ni ko ba mi lo

Duro timi o, Ololufe

Ife ti ko labawon ni ko ba mi lo

Duro timi o, Ololufe

Ife ti ko leetan rara ni ko ba mi lo

Duro timi o, Ololufe

Ife ti ko labuku ni ko ba mi lo

Shola Allyson Eji Owuro Lyrics

Did you find apk for android? You can find new Free Android Games and apps.

Leave a Comment