Shola Allyson Adura Ololufe Lyrics

Want create site? Find Free WordPress Themes and plugins.

Shola Allyson Adura Ololufe Lyrics

Adura mogba fun e ololufe mi

Ire ni mo n su fun e ayanfe oko mi ore mi

Oo ni kagbako l’aye oo ni r’ogun akoba

 

Oo ni s’irin l’aye be oo ni t’oju ile mole

Ainif’okanbale o ni y’odo re lailailailailai

Oo ni m’osi l’aye aye re a ma dara si

Ife eledumare ree e ooo ore mi

O fewa fun re o fewa f’ayo taa ba barawa s’otito

Angeli alayo mi faramo tire nse ni won njo s’ise

Iranse alaanu re wa pelu t’emi nwon njo rin po ni

Ibaase ‘wo layo pupo latagbala eledumare

Wa inu oluwa aa dun si Ibaase’ wo layo pupo

Latagbala eledumare wa o inu oluwa aa dun si wa

 

Oba ni a lowo a bi’mo

Oba ni a s’owo a j’ere

Oba ni a r’aje jeun

Imole aa ma tan si

Oba ni a lowo a bi’mo

Oba ni a s’owo a j’ere

Oba ni a r’aje jeun

Imole aa ma tan si

 

 

Imoran mi ree fun e ooo oloro mi

Imoran ni mo n gba e ninu ife to jin oloro mi maa gbo

Pe ko maa s’ora se ore mi at’orun s’ora se

Jowo f’arabale ko gb’emi olorun

L’aye ko m’okan at’eti re kuro ninu etan to kun’nu aye

Gbogbo ohun to ma n dan ko ni wura

Joo ma fi ididi w’ola ola aa to ni wa

Fitila ona re o ni ku lailai aye re a ma dara si

 

Owo o ni wan n’ile wa

Owo Olorun nbe lara wa

Owo Oluwa nba wa lo

Imole a ma tan si

Oba ni a lowo a bi’mo

Oba ni a s’owo a j’ere

Oba ni a r’aje jeun

Imole aa ma tan si

 

 

Ope ti mo nda l’ojojumo ree ore okan t’eledua fun mi maa gbo

Modupe mo yin’le f’olu to gbe mi pade alaanu

Mosope mi o kuta l’oju oja ife, eleda lo ba mi se

Alabarin t’eledua yan fun o gangan ni moje

Alabase t’olorun fifun mi gangan ni iwo je

Ajose wa a maa mayo wa o nfun wa l’ayo

Ka sa maa sora se ajose wa a maa mayo wa

Ka sa maa sora se

 

Oba ni a lowo a bi’mo

Oba ni a s’owo a j’ere

Oba ni a r’aje jeun

Imole aa ma tan si

Oba ni a lowo a bi’mo

Oba ni a s’owo a j’ere

Oba ni a r’aje jeun

Imole aa ma tan si

 

 

Ife okan mi ree ore okan mi tipetipe maa gbo

Pe ka je imole

Imole wa ko tan f’araye ri

Ka f’ara wa lowo

Ka jo rin f’olu ka nipa rere f’ayo

Eni waye lai mu’fe orun se asan bansa

Aa r’owo lo aa f’ola we

Ka s’ise taa ran wa wa pa bi fun

Ajose wa a maa mayo wa o nfun wa l’ayo ka sa maa sora se

Ajose wa a maa mayo wa

Ka sa maa sora se

 

Ajose wa a maa mayo wa

Ka sa maa sora se

Ajose wa a maa mayo wa

Ka sa maa sora se

Ajose wa a maa mayo wa

Ka sa maa sora se

Ka sa maa sora se

Ka sa maa sora se

Ka sa maa sora se

Ka sa maa sora se

Ka sa maa sora se

Ka sa maa sora se

Ka sa maa sora se

Ka sa maa sora se

Ka sa maa sora se

Ka sa maa sora se

Shola Allyson Adura Ololufe Lyrics

Did you find apk for android? You can find new Free Android Games and apps.

Leave a Comment