Shola Allyson Adun Lyrics

Want create site? Find Free WordPress Themes and plugins.

Shola Allyson Adun Lyrics

Iran odun u ti mo ri re oo

Ifihan ti mogba to yo simi ni yi ooo

Adun a po fun mi ona a ma la daada

 

Mori adun mo ladu were ladun wole de

Eyi mo bere ni mori oluda mi sope

Edumare fadun s’ola mi modupe adun ni

Mori adun mo ladu were ladun wole de

Eyi mo bere ni mori oluda mi sope

Edumare fadun s’ola mi modupe adun ni

 

 

Mo gb’adun de ooo e tewo, e wa gba.

Eni ba fe koteti  oludani lo gbese to po gan ran mi wa

Boju woke ko r’adun  emi boju woke mo r’adun.

ilakaka o sa simbe  orun logbadun yen wa.

 

Iran odunu ti mo ri re oo

Ifihan ti mogba to yo simi ni yi ooo

Adun a po fun miona a ma la daada

 

Beee ni

 

Mori adun mo ladu were ladun wole de

Eyi mo bere ni mori oluda mi sope

Edumare fadun s’ola mi modupe adun ni

Mori adun mo ladu were ladun wole de

Eyi mo bere ni mori oluda mi sope

Edumare fadun s’ola mi modupe adun ni

 

Eni ba feran iyan ko ya sore oni su

Eni ba kudun eko yore alagbado

Eni ma ri aiye gbe pelu adun

Oni lati sore ninu oba oke to laiye

Ohun ladun lodo adun ti ba ni kale

 

Iran odunu ti mo ri re oo

Ifihan ti mogba to yo simi ni yi ooo

Adun a po fun miona a ma la dada

 

Beeni

 

Mori adun mo ladu were ladun wole de

Eyi mo bere ni mori oluda mi sope

Edumare fadun s’ola mi modupe adun ni

Mori adun mo ladu were ladun wole de

Eyi mo bere ni mori oluda mi sope

Edumare fadun s’ola mi modupe adun ni

 

Emi ti adun yi gba o koni te ko ni  bo

Eleda lo funmi ladun ona mi a la ko ni di

Odo ikan ti mo mo ti mo sola ko ni gbe ko ni dajun

Alafia adun ede mi ni won gbe

Ire lapa otun adun lapa osi mi

Ibukun po ni waju oro lo tele beeni

 

Mori adun mo ladu were ladun wole de

Eyi mo bere ni mori oluda mi sope

Edumare fadun s’ola mi modupe adun ni

Mori adun mo ladu were ladun wole de

Eyi mo bere ni mori oluda mi sope

Edumare fadun s’ola mi modupe adun ni

 

Adun yi a ba mi kale

Adun a bami kale

Eledumare lo fun mi orun leja ti wa

Adun yi a bami kale

Mo ladu mori adun mo rigba lo

Adun yi a bami kale

Ibukun oluwa lo mu ni la laisi lala

Adun yi a bami kale

Mo fi enu ayowi temi mo fi enu ola wi temi

Adun yi a bami kale

 

Mori adun mo ladu were ladun wole de

Eyi mo bere ni mori oluda mi sope

Edumare fadun s’ola mi modupe adun ni

Mori adun mo ladu were ladun wole de

Eyi mo bere ni mori oluda mi sope

Edumare fadun s’ola mi modupe adun ni

Edumare fadun s’ola mi modupe adun ni

Edumare fadun s’ola mi modupe adun ni

 

Ibanuje ko ma gbe ibi towa modupe adun ni

Moradun moladun modupe adun ni

Afi enu mi pere mo ra mi modupe duni

Edumare fadun s’ola mi modupe adun ni

Edumare fadun s’ola mi modupe adun ni

 

Imole tan sona mo dupe adun

Temi dun modupe adun ni

Edumare fadun s’ola mi modupe adun ni

Adun yi a bami kale modupe adun ni

Ma ri gba lo ma rona lo modupe adun ni

Adun a pelu ire mi adun a pelu ogo mo modupe adun ni

Edumare fadun s’ola mi modupe adun ni

Adun adun adun adun adun kale modupe adun ni

Koni koro fun mi o modupe adun ni

Edumare fadun s’ola mi modupe adun ni

Edumare fadun s’ola mi modupe adun ni

Shola Allyson Adun Lyrics

Did you find apk for android? You can find new Free Android Games and apps.

Leave a Comment